Surah Al-Qari'ah in Yoruba: translation and audio
Surah 101 · القارعة · The Calamity · 11 verses
Surah Al-Qari'ah verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Al-Qari'ah word by word in English.
Verse 1
ٱلْقَارِعَةُ
Transliteration al-qāriʿatu
Yoruba Àkókò ìjáyà.
Verse 2
مَا ٱلْقَارِعَةُ
Transliteration mā l-qāriʿatu
Yoruba Kí ni Àkókò ìjáyà?
Verse 3
وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا ٱلْقَارِعَةُ
Transliteration wamā adrāka mā l-qāriʿatu
Yoruba Kí sì l’ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Àkókò ìjáyà?
Verse 4
يَوْمَ يَكُونُ ٱلنَّاسُ كَٱلْفَرَاشِ ٱلْمَبْثُوثِ
Transliteration yawma yakūnu l-nāsu kal-farāshi l-mabthūthi
Yoruba (Òhun ni) ọjọ́ tí ènìyàn yó dà bí àfòpiná tí wọ́n fọ́nká síta,
Verse 5
وَتَكُونُ ٱلْجِبَالُ كَٱلْعِهْنِ ٱلْمَنفُوشِ
Transliteration watakūnu l-jibālu kal-ʿih'ni l-manfūshi
Yoruba àwọn àpáta yó sì dà bí ẹ̀gbọ̀n òwú tí wọ́n gbọ̀n dànù.
Verse 6
فَأَمَّا مَن ثَقُلَتْ مَوَٰزِينُهُۥ
Transliteration fa-ammā man thaqulat mawāzīnuhu
Yoruba Nítorí náà, ní ti ẹni tí òṣùwọ̀n (iṣẹ́ rere) rẹ̀ bá tẹ̀wọ̀n,
Verse 7
فَهُوَ فِى عِيشَةٍ رَّاضِيَةٍ
Transliteration fahuwa fī ʿīshatin rāḍiyatin
Yoruba ó sì máa wà nínú ìṣẹ̀mí tó máa yọ́nú sí.
Verse 8
وَأَمَّا مَنْ خَفَّتْ مَوَٰزِينُهُۥ
Transliteration wa-ammā man khaffat mawāzīnuhu
Yoruba Ní ti ẹni tí òṣùwọ̀n (iṣẹ́ rere) rẹ̀ bá sì fúyẹ́,
Verse 9
فَأُمُّهُۥ هَاوِيَةٌ
Transliteration fa-ummuhu hāwiyatun
Yoruba Hāwiyah sì ni ibùgbé rẹ̀.
Verse 10
وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا هِيَهْ
Transliteration wamā adrāka mā hiyah
Yoruba Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ bẹ́ẹ̀?
Verse 11
نَارٌ حَامِيَةٌۢ
Transliteration nārun ḥāmiyatun
Yoruba (Òhun ni) Iná gbígbóná tó ń jó gan-an.
Read Surah Al-Qari'ah in another language
- English (word by word)
- Albanian
- Amazigh
- Amharic
- Assamese
- Azerbaijani
- Bambara
- Bangla
- Bosnian
- Bulgarian
- Chechen
- Chinese
- Czech
- Dari
- Dhivehi
- Dutch
- Finnish
- French
- German
- Gujarati
- Hausa
- Hebrew
- Hindi
- Indonesian
- Italian
- Japanese
- Kannada
- Kazakh
- Khmer
- Kinyarwanda
- Korean
- Kurdish
- Luganda
- Malay
- Malayalam
- Maranao
- Marathi
- Nepali
- Norwegian
- Oromo
- Pashto
- Persian
- Polish
- Portuguese
- Romanian
- Russian
- Sindhi
- Sinhala
- Somali
- Spanish
- Swahili
- Swedish
- Tagalog
- Tajik
- Tamil
- Tatar
- Telugu
- Thai
- Turkish
- Ukrainian
- Urdu
- Uyghur
- Uzbek
- Vietnamese
- Yao
All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.
Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.