Surah Ad-Duhaa in Yoruba: translation and audio
Surah 93 · الضحى · The Morning Hours · 11 verses
Surah Ad-Duhaa verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Ad-Duhaa word by word in English.
Verse 1
وَٱلضُّحَىٰ
Transliteration wal-ḍuḥā
Yoruba Allāhu fi ìyálẹ̀ta búra.
Verse 2
وَٱلَّيْلِ إِذَا سَجَىٰ
Transliteration wa-al-layli idhā sajā
Yoruba Ó tún fi alẹ́ nígbà tí (ilẹ̀) bá ṣú búra.
Verse 3
مَا وَدَّعَكَ رَبُّكَ وَمَا قَلَىٰ
Transliteration mā waddaʿaka rabbuka wamā qalā
Yoruba Olúwa rẹ kò pa ọ́ tì, kò sì bínú sí ọ.
Verse 4
وَلَلْـَٔاخِرَةُ خَيْرٌ لَّكَ مِنَ ٱلْأُولَىٰ
Transliteration walalākhiratu khayrun laka mina l-ūlā
Yoruba Dájúdájú ọ̀run lóore fún ọ ju ayé.
Verse 5
وَلَسَوْفَ يُعْطِيكَ رَبُّكَ فَتَرْضَىٰٓ
Transliteration walasawfa yuʿ'ṭīka rabbuka fatarḍā
Yoruba Dájúdájú láìpẹ́ Olúwa rẹ máa fún ọ ní (oore púpọ̀ ní ọ̀run). Nítorí náà, o sì máa yọ́nú sí i.
Verse 6
أَلَمْ يَجِدْكَ يَتِيمًا فَـَٔاوَىٰ
Transliteration alam yajid'ka yatīman faāwā
Yoruba Ṣé (Allāhu) kò rí ọ ní ọmọ-òrukàn ni? Ó sì fún ọ ní ibùgbé.
Verse 7
وَوَجَدَكَ ضَآلًّا فَهَدَىٰ
Transliteration wawajadaka ḍāllan fahadā
Yoruba Ó sì rí ọ ní aláìmọ̀nà (ìyẹn ṣíwájú ìsọ̀kalẹ̀ ìmísí). Ó sì fi ọ̀nà mọ̀ ọ́.1
Verse 8
وَوَجَدَكَ عَآئِلًا فَأَغْنَىٰ
Transliteration wawajadaka ʿāilan fa-aghnā
Yoruba Ó tún rí ọ ní aláìní, Ó sì rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀.
Verse 9
فَأَمَّا ٱلْيَتِيمَ فَلَا تَقْهَرْ
Transliteration fa-ammā l-yatīma falā taqhar
Yoruba Nítorí náà, ní ti ọmọ-òrukàn, má ṣe jẹ gàba (lé e lórí).
Verse 10
وَأَمَّا ٱلسَّآئِلَ فَلَا تَنْهَرْ
Transliteration wa-ammā l-sāila falā tanhar
Yoruba Ní ti alágbe, má sì ṣe jágbe (mọ́ ọn).
Verse 11
وَأَمَّا بِنِعْمَةِ رَبِّكَ فَحَدِّثْ
Transliteration wa-ammā biniʿ'mati rabbika faḥaddith
Yoruba Ní ti ìdẹ̀ra Olúwa rẹ, sọ ọ́ jáde.
Read Surah Ad-Duhaa in another language
- English (word by word)
- Albanian
- Amazigh
- Amharic
- Assamese
- Azerbaijani
- Bambara
- Bangla
- Bosnian
- Bulgarian
- Chechen
- Chinese
- Czech
- Dari
- Dhivehi
- Dutch
- Finnish
- French
- German
- Gujarati
- Hausa
- Hebrew
- Hindi
- Indonesian
- Italian
- Japanese
- Kannada
- Kazakh
- Khmer
- Kinyarwanda
- Korean
- Kurdish
- Luganda
- Malay
- Malayalam
- Maranao
- Marathi
- Nepali
- Norwegian
- Oromo
- Pashto
- Persian
- Polish
- Portuguese
- Romanian
- Russian
- Sindhi
- Sinhala
- Somali
- Spanish
- Swahili
- Swedish
- Tagalog
- Tajik
- Tamil
- Tatar
- Telugu
- Thai
- Turkish
- Ukrainian
- Urdu
- Uyghur
- Uzbek
- Vietnamese
- Yao
All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.
Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.