Surah At-Tariq in Yoruba: translation and audio
Surah 86 · الطارق · The Nightcommer · 17 verses
Surah At-Tariq verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah At-Tariq word by word in English.
Verse 1
وَٱلسَّمَآءِ وَٱلطَّارِقِ
Transliteration wal-samāi wal-ṭāriqi
Yoruba (Allāhu) fi sánmọ̀ àti Tọ̄riƙ búra.
Verse 2
وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا ٱلطَّارِقُ
Transliteration wamā adrāka mā l-ṭāriqu
Yoruba Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Tọ̄riƙ?
Verse 3
ٱلنَّجْمُ ٱلثَّاقِبُ
Transliteration al-najmu l-thāqibu
Yoruba Ìràwọ̀ tí ìmọ́lẹ̀ rẹ̀ ń tàn ròrò (ní alẹ́ ni).
Verse 4
إِن كُلُّ نَفْسٍ لَّمَّا عَلَيْهَا حَافِظٌ
Transliteration in kullu nafsin lammā ʿalayhā ḥāfiẓun
Yoruba Kò sí ẹ̀mí kan àfi kí ẹ̀ṣọ́ kan wà fún un (nínú àwọn mọlāika).
Verse 5
فَلْيَنظُرِ ٱلْإِنسَـٰنُ مِمَّ خُلِقَ
Transliteration falyanẓuri l-insānu mimma khuliqa
Yoruba Nítorí náà, kí ènìyàn wòye sí ohun tí A fi ṣẹ̀dá rẹ̀.
Verse 6
خُلِقَ مِن مَّآءٍ دَافِقٍ
Transliteration khuliqa min māin dāfiqin
Yoruba Wọ́n ṣẹ̀dá rẹ̀ láti inú omi tó ń tú jáde kọ̀ọ́kọ̀ọ́.
Verse 7
يَخْرُجُ مِنۢ بَيْنِ ٱلصُّلْبِ وَٱلتَّرَآئِبِ
Transliteration yakhruju min bayni l-ṣul'bi wal-tarāibi
Yoruba Ó ń jáde láti ààrin ìbàdí ọkùnrin àti àwọn ẹfọ́nhà igbá-àyà obìnrin.
Verse 8
إِنَّهُۥ عَلَىٰ رَجْعِهِۦ لَقَادِرٌ
Transliteration innahu ʿalā rajʿihi laqādirun
Yoruba Dájúdájú Allāhu ni Alágbára lóri ìdápadà rẹ̀
Verse 9
يَوْمَ تُبْلَى ٱلسَّرَآئِرُ
Transliteration yawma tub'lā l-sarāiru
Yoruba ní ọjọ́ tí wọ́n máa ṣe àyẹ̀wò àwọn (iṣẹ́) àṣepamọ́.
Verse 10
فَمَا لَهُۥ مِن قُوَّةٍ وَلَا نَاصِرٍ
Transliteration famā lahu min quwwatin walā nāṣirin
Yoruba Nígbà náà, kò níí sí agbára tàbí alárànṣe kan fún un.
Verse 11
وَٱلسَّمَآءِ ذَاتِ ٱلرَّجْعِ
Transliteration wal-samāi dhāti l-rajʿi
Yoruba Allāhu fi sánmọ̀ tó ń rọ òjò ní ọdọọdún búra.
Verse 12
وَٱلْأَرْضِ ذَاتِ ٱلصَّدْعِ
Transliteration wal-arḍi dhāti l-ṣadʿi
Yoruba Ó tún fi ilẹ̀ tó ń sán kànkàn (fún híhùjáde èso) búra.
Verse 13
إِنَّهُۥ لَقَوْلٌ فَصْلٌ
Transliteration innahu laqawlun faṣlun
Yoruba Dájúdájú al-Ƙur’ān ni ọ̀rọ̀-ìpínyà (láààrin òdodo àti irọ́).
Verse 14
وَمَا هُوَ بِٱلْهَزْلِ
Transliteration wamā huwa bil-hazli
Yoruba Kì í sì ṣe àwàdà.
Verse 15
إِنَّهُمْ يَكِيدُونَ كَيْدًا
Transliteration innahum yakīdūna kaydan
Yoruba Dájúdájú wọ́n ń déte gan-an.
Verse 16
وَأَكِيدُ كَيْدًا
Transliteration wa-akīdu kaydan
Yoruba Èmi náà sì ń déte gan-an.1
Verse 17
فَمَهِّلِ ٱلْكَـٰفِرِينَ أَمْهِلْهُمْ رُوَيْدًۢا
Transliteration famahhili l-kāfirīna amhil'hum ruwaydan
Yoruba Nítorí náà, lọ́ra fún àwọn aláìgbàgbọ́. Lọ́ wọn lára sẹ́ fún ìgbà díẹ̀.
Read Surah At-Tariq in another language
- English (word by word)
- Albanian
- Amazigh
- Amharic
- Assamese
- Azerbaijani
- Bambara
- Bangla
- Bosnian
- Bulgarian
- Chechen
- Chinese
- Czech
- Dari
- Dhivehi
- Dutch
- Finnish
- French
- German
- Gujarati
- Hausa
- Hebrew
- Hindi
- Indonesian
- Italian
- Japanese
- Kannada
- Kazakh
- Khmer
- Kinyarwanda
- Korean
- Kurdish
- Luganda
- Malay
- Malayalam
- Maranao
- Marathi
- Nepali
- Norwegian
- Oromo
- Pashto
- Persian
- Polish
- Portuguese
- Romanian
- Russian
- Sindhi
- Sinhala
- Somali
- Spanish
- Swahili
- Swedish
- Tagalog
- Tajik
- Tamil
- Tatar
- Telugu
- Thai
- Turkish
- Ukrainian
- Urdu
- Uyghur
- Uzbek
- Vietnamese
- Yao
All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.
Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.