Surah An-Nas in Yoruba: translation and audio
Surah 114 · الناس · Mankind · 6 verses
Surah An-Nas verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah An-Nas word by word in English.
Verse 1
قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلنَّاسِ
Transliteration qul aʿūdhu birabbi l-nāsi
Yoruba Sọ pé: “Mo sá di Olúwa àwọn ènìyàn,
Verse 2
مَلِكِ ٱلنَّاسِ
Transliteration maliki l-nāsi
Yoruba Ọba àwọn ènìyàn,
Verse 3
إِلَـٰهِ ٱلنَّاسِ
Transliteration ilāhi l-nāsi
Yoruba Ọlọ́hun àwọn ènìyàn,1
Verse 4
مِن شَرِّ ٱلْوَسْوَاسِ ٱلْخَنَّاسِ
Transliteration min sharri l-waswāsi l-khanāsi
Yoruba níbi aburú (Èṣù) oníròyíròyí, olùsásẹ́yìn (fún ẹni tó bá ń dárúkọ Allāhu.
Verse 5
ٱلَّذِى يُوَسْوِسُ فِى صُدُورِ ٱلنَّاسِ
Transliteration alladhī yuwaswisu fī ṣudūri l-nāsi
Yoruba (Èṣù ni) ẹni tí ó ń kó ròyíròyí sínú àwọn ọkàn ènìyàn.
Verse 6
مِنَ ٱلْجِنَّةِ وَٱلنَّاسِ
Transliteration mina l-jinati wal-nāsi
Yoruba (Èṣù náà) wà nínú àwọn àlùjànnú àti àwọn ènìyàn.”
Read Surah An-Nas in another language
- English (word by word)
- Albanian
- Amazigh
- Amharic
- Assamese
- Azerbaijani
- Bambara
- Bangla
- Bosnian
- Bulgarian
- Chechen
- Chinese
- Czech
- Dari
- Dhivehi
- Dutch
- Finnish
- French
- German
- Gujarati
- Hausa
- Hebrew
- Hindi
- Indonesian
- Italian
- Japanese
- Kannada
- Kazakh
- Khmer
- Kinyarwanda
- Korean
- Kurdish
- Luganda
- Malay
- Malayalam
- Maranao
- Marathi
- Nepali
- Norwegian
- Oromo
- Pashto
- Persian
- Polish
- Portuguese
- Romanian
- Russian
- Sindhi
- Sinhala
- Somali
- Spanish
- Swahili
- Swedish
- Tagalog
- Tajik
- Tamil
- Tatar
- Telugu
- Thai
- Turkish
- Ukrainian
- Urdu
- Uyghur
- Uzbek
- Vietnamese
- Yao
All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.
Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.