MyDugsiStart learning

Surah Al-Ma'un in Yoruba: translation and audio

Surah 107 · الماعون · The Small kindnesses · 7 verses

Surah Al-Ma'un verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Al-Ma'un word by word in English.

Verse 1

أَرَءَيْتَ ٱلَّذِى يُكَذِّبُ بِٱلدِّينِ

Transliteration ara-ayta alladhī yukadhibu bil-dīni

Yoruba Sọ fún mi nípa ẹni tó ń pe Ọjọ́ Ẹ̀san ní irọ́!

Verse 2

فَذَٰلِكَ ٱلَّذِى يَدُعُّ ٱلْيَتِيمَ

Transliteration fadhālika alladhī yaduʿʿu l-yatīma

Yoruba Ìyẹn ni ẹni tó ń lé ọmọ-òrukàn dànù.

Verse 3

وَلَا يَحُضُّ عَلَىٰ طَعَامِ ٱلْمِسْكِينِ

Transliteration walā yaḥuḍḍu ʿalā ṭaʿāmi l-mis'kīni

Yoruba Kò sì níí gbìyànjú láti bọ́ mẹ̀kúnnù.

Verse 4

فَوَيْلٌ لِّلْمُصَلِّينَ

Transliteration fawaylun lil'muṣallīna

Yoruba Ègbé ni fún àwọn (mùnááfìkí) tó ń kírun;1

Verse 5

ٱلَّذِينَ هُمْ عَن صَلَاتِهِمْ سَاهُونَ

Transliteration alladhīna hum ʿan ṣalātihim sāhūna

Yoruba àwọn tó ń gbàgbé láti kírun wọn ní àsìkò rẹ̀;

Verse 6

ٱلَّذِينَ هُمْ يُرَآءُونَ

Transliteration alladhīna hum yurāūna

Yoruba àwọn tó ń ṣe ṣekárími;

Verse 7

وَيَمْنَعُونَ ٱلْمَاعُونَ

Transliteration wayamnaʿūna l-māʿūna

Yoruba àti pé wọ́n ń hánnà ohun èlò (fún àwọn ènìyàn).

Read Surah Al-Ma'un in another language

All languages

All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.

Learn it in MyDugsi

Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.