Surah Al-'Adiyat in Yoruba: translation and audio
Surah 100 · العاديات · The Courser · 11 verses
Surah Al-'Adiyat verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Al-'Adiyat word by word in English.
Verse 1
وَٱلْعَـٰدِيَـٰتِ ضَبْحًا
Transliteration wal-ʿādiyāti ḍabḥan
Yoruba Allāhu fi àwọn ẹṣin tó ń sáré tó ń mí hẹlẹhẹlẹ ní ojú-ogun búra.
Verse 2
فَٱلْمُورِيَـٰتِ قَدْحًا
Transliteration fal-mūriyāti qadḥan
Yoruba Ó tún fi àwọn ẹṣin tí pátákò ẹsẹ̀ wọn ń ṣáná (níbi eré sísá) búra.
Verse 3
فَٱلْمُغِيرَٰتِ صُبْحًا
Transliteration fal-mughīrāti ṣub'ḥan
Yoruba Ó tún fi àwọn ẹṣin tó ń kọlu ọ̀tá ẹ̀sìn ní òwúrọ̀ kùtùkùtù búra.
Verse 4
فَأَثَرْنَ بِهِۦ نَقْعًا
Transliteration fa-atharna bihi naqʿan
Yoruba Wọ́n sì fi (pátákò ẹsẹ̀ wọn) tu eruku (ilẹ̀ ọ̀tá) sókè.
Verse 5
فَوَسَطْنَ بِهِۦ جَمْعًا
Transliteration fawasaṭna bihi jamʿan
Yoruba Wọ́n tún bẹ́ gìjà pẹ̀lú eruku ẹsẹ̀ wọn sáààrin àkójọ ọ̀tá.
Verse 6
إِنَّ ٱلْإِنسَـٰنَ لِرَبِّهِۦ لَكَنُودٌ
Transliteration inna l-insāna lirabbihi lakanūdun
Yoruba Dájúdájú ènìyàn ni aláìmoore sí Olúwa rẹ̀.
Verse 7
وَإِنَّهُۥ عَلَىٰ ذَٰلِكَ لَشَهِيدٌ
Transliteration wa-innahu ʿalā dhālika lashahīdun
Yoruba Dájúdájú Allāhu sì ń jẹ́ Ẹlẹ́rìí lórí ìyẹn.
Verse 8
وَإِنَّهُۥ لِحُبِّ ٱلْخَيْرِ لَشَدِيدٌ
Transliteration wa-innahu liḥubbi l-khayri lashadīdun
Yoruba Àti pé dájúdájú ènìyàn le gan-an níbi ìfẹ́ oore ayé.
Verse 9
۞ أَفَلَا يَعْلَمُ إِذَا بُعْثِرَ مَا فِى ٱلْقُبُورِ
Transliteration afalā yaʿlamu idhā buʿ'thira mā fī l-qubūri
Yoruba Ṣé kò mọ̀ pé nígbà tí wọ́n bá tú ohun tó wà nínú sàréè jáde (fún àjíǹde),
Verse 10
وَحُصِّلَ مَا فِى ٱلصُّدُورِ
Transliteration waḥuṣṣila mā fī l-ṣudūri
Yoruba tí wọ́n sì tú ohun tó wà nínú igbá-àyà ẹ̀dá síta pátápátá,
Verse 11
إِنَّ رَبَّهُم بِهِمْ يَوْمَئِذٍ لَّخَبِيرٌۢ
Transliteration inna rabbahum bihim yawma-idhin lakhabīrun
Yoruba dájúdájú Olúwa wọn ni Alámọ̀tán nípa wọn ní Ọjọ́ yẹn?
Read Surah Al-'Adiyat in another language
- English (word by word)
- Albanian
- Amazigh
- Amharic
- Assamese
- Azerbaijani
- Bambara
- Bangla
- Bosnian
- Bulgarian
- Chechen
- Chinese
- Czech
- Dari
- Dhivehi
- Dutch
- Finnish
- French
- German
- Gujarati
- Hausa
- Hebrew
- Hindi
- Indonesian
- Italian
- Japanese
- Kannada
- Kazakh
- Khmer
- Kinyarwanda
- Korean
- Kurdish
- Luganda
- Malay
- Malayalam
- Maranao
- Marathi
- Nepali
- Norwegian
- Oromo
- Pashto
- Persian
- Polish
- Portuguese
- Romanian
- Russian
- Sindhi
- Sinhala
- Somali
- Spanish
- Swahili
- Swedish
- Tagalog
- Tajik
- Tamil
- Tatar
- Telugu
- Thai
- Turkish
- Ukrainian
- Urdu
- Uyghur
- Uzbek
- Vietnamese
- Yao
All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.
Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.