MyDugsiStart learning

Surah Al-Humazah in Yoruba: translation and audio

Surah 104 · الهمزة · The Traducer · 9 verses

Surah Al-Humazah verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Al-Humazah word by word in English.

Verse 1

وَيْلٌ لِّكُلِّ هُمَزَةٍ لُّمَزَةٍ

Transliteration waylun likulli humazatin lumazatin

Yoruba Ègbé ni fún gbogbo abúnilójú-ẹni, abúnilẹ́yìn-ẹni,

Verse 2

ٱلَّذِى جَمَعَ مَالًا وَعَدَّدَهُۥ

Transliteration alladhī jamaʿa mālan waʿaddadahu

Yoruba ẹni tí ó kó dúkìá jọ, tí ó sì kà á lákàtúnkà (láì ná an fún ẹ̀sìn).

Verse 3

يَحْسَبُ أَنَّ مَالَهُۥٓ أَخْلَدَهُۥ

Transliteration yaḥsabu anna mālahu akhladahu

Yoruba Ó ń lérò pé dájúdájú dúkìá rẹ̀ yóò mú un ṣe gbére (nílé ayé).

Verse 4

كَلَّا ۖ لَيُنۢبَذَنَّ فِى ٱلْحُطَمَةِ

Transliteration kallā layunbadhanna fī l-ḥuṭamati

Yoruba Rárá (kò rí bẹ́ẹ̀). Dájúdájú wọ́n máa kù ú lókò sínú Hutọmọh ni.

Verse 5

وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا ٱلْحُطَمَةُ

Transliteration wamā adrāka mā l-ḥuṭamatu

Yoruba Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Hutọmọh?

Verse 6

نَارُ ٱللَّهِ ٱلْمُوقَدَةُ

Transliteration nāru l-lahi l-mūqadatu

Yoruba (Òhun ni) Iná Allāhu tí wọ́n ń kò (tó ń jó geregere),

Verse 7

ٱلَّتِى تَطَّلِعُ عَلَى ٱلْأَفْـِٔدَةِ

Transliteration allatī taṭṭaliʿu ʿalā l-afidati

Yoruba èyí tí ó máa jó (ẹ̀dá) wọ inú ọkàn lọ.

Verse 8

إِنَّهَا عَلَيْهِم مُّؤْصَدَةٌ

Transliteration innahā ʿalayhim mu'ṣadatun

Yoruba Dájúdájú wọ́n máa ti (àwọn ìlẹ̀kùn) Iná pa mọ́ wọn lórí pátápátá.

Verse 9

فِى عَمَدٍ مُّمَدَّدَةٍۭ

Transliteration fī ʿamadin mumaddadatin

Yoruba (Wọ́n máa wà) láààrin àwọn òpó kìrìbìtì gíga (nínú Iná).

Read Surah Al-Humazah in another language

All languages

All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.

Learn it in MyDugsi

Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.