MyDugsiStart learning

Surah Ash-Sharh in Yoruba: translation and audio

Surah 94 · الشرح · The Relief · 8 verses

Surah Ash-Sharh verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Ash-Sharh word by word in English.

Verse 1

أَلَمْ نَشْرَحْ لَكَ صَدْرَكَ

Transliteration alam nashraḥ laka ṣadraka

Yoruba Ṣé A kò ṣípayá igbá-àyà rẹ fún ọ bí?

Verse 2

وَوَضَعْنَا عَنكَ وِزْرَكَ

Transliteration wawaḍaʿnā ʿanka wiz'raka

Yoruba A sì gbé ẹ̀ṣẹ̀ rẹ kúrò lọ́rùn rẹ,

Verse 3

ٱلَّذِىٓ أَنقَضَ ظَهْرَكَ

Transliteration alladhī anqaḍa ẓahraka

Yoruba èyí tí ó wọ̀ ọ́ lọ́rùn.1

Verse 4

وَرَفَعْنَا لَكَ ذِكْرَكَ

Transliteration warafaʿnā laka dhik'raka

Yoruba A sì gbé ìrántí orúkọ rẹ ga fún ọ.

Verse 5

فَإِنَّ مَعَ ٱلْعُسْرِ يُسْرًا

Transliteration fa-inna maʿa l-ʿus'ri yus'ran

Yoruba Nítorí náà, dájúdájú ìdẹ̀kùn wà lẹ́yìn ìnira.

Verse 6

إِنَّ مَعَ ٱلْعُسْرِ يُسْرًا

Transliteration inna maʿa l-ʿus'ri yus'ran

Yoruba Dájúdájú ìdẹ̀kùn wà lẹ́yìn ìnira sẹ́.

Verse 7

فَإِذَا فَرَغْتَ فَٱنصَبْ

Transliteration fa-idhā faraghta fa-inṣab

Yoruba Nítorí náà, nígbà tí o bá bùṣe (lórí ohun tí ó jẹmọ́ táyé), gbìyànjú (dáadáa lórí ìjọ́sìn).

Verse 8

وَإِلَىٰ رَبِّكَ فَٱرْغَب

Transliteration wa-ilā rabbika fa-ir'ghab

Yoruba Ọ̀dọ̀ Olúwa rẹ sì ni kí o ṣojú kòkòrò oore sí.

Read Surah Ash-Sharh in another language

All languages

All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.

Learn it in MyDugsi

Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.