MyDugsiStart learning

Surah Al-Masad in Yoruba: translation and audio

Surah 111 · المسد · The Palm Fiber · 5 verses

Surah Al-Masad verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Al-Masad word by word in English.

Verse 1

تَبَّتْ يَدَآ أَبِى لَهَبٍ وَتَبَّ

Transliteration tabbat yadā abī lahabin watabba

Yoruba Ọwọ́ Abu-Lahab méjèèjì ti ṣòfò. Òun náà sì ṣòfò.

Verse 2

مَآ أَغْنَىٰ عَنْهُ مَالُهُۥ وَمَا كَسَبَ

Transliteration mā aghnā ʿanhu māluhu wamā kasaba

Yoruba Àwọn dúkìá rẹ̀ àti ohun tí ó ṣe níṣẹ́ (ìyẹn, àwọn ọmọ rẹ̀) kò sì níí rọ̀ ọ́ lọ́rọ̀ (níbi ìyà).

Verse 3

سَيَصْلَىٰ نَارًا ذَاتَ لَهَبٍ

Transliteration sayaṣlā nāran dhāta lahabin

Yoruba Ó sì máa wọ inú Iná eléjò fòfò.

Verse 4

وَٱمْرَأَتُهُۥ حَمَّالَةَ ٱلْحَطَبِ

Transliteration wa-im'ra-atuhu ḥammālata l-ḥaṭabi

Yoruba Àti ìyàwó rẹ̀, aláàárù-igi-ìṣẹ́pẹ́ ẹlẹ́gùn-ún, (ó máa wọná).

Verse 5

فِى جِيدِهَا حَبْلٌ مِّن مَّسَدٍۭ

Transliteration fī jīdihā ḥablun min masadin

Yoruba Igbà-ọ̀pẹ pọ̀npọ̀nràn máa wà ní ọrùn rẹ̀ (nínú Iná).

Read Surah Al-Masad in another language

All languages

All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.

Learn it in MyDugsi

Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.