MyDugsiStart learning

Surah Al-Falaq in Yoruba: translation and audio

Surah 113 · الفلق · The Daybreak · 5 verses

Surah Al-Falaq verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Al-Falaq word by word in English.

Verse 1

قُلْ أَعُوذُ بِرَبِّ ٱلْفَلَقِ

Transliteration qul aʿūdhu birabbi l-falaqi

Yoruba Sọ pé: “Mo sá di Olúwa òwúrọ̀ kùtùkùtù

Verse 2

مِن شَرِّ مَا خَلَقَ

Transliteration min sharri mā khalaqa

Yoruba níbi aburú ohun tí Ó dá,1

Verse 3

وَمِن شَرِّ غَاسِقٍ إِذَا وَقَبَ

Transliteration wamin sharri ghāsiqin idhā waqaba

Yoruba àti níbi aburú òru nígbà tí ó bá ṣóòkùn,

Verse 4

وَمِن شَرِّ ٱلنَّفَّـٰثَـٰتِ فِى ٱلْعُقَدِ

Transliteration wamin sharri l-nafāthāti fī l-ʿuqadi

Yoruba àti níbi aburú àwọn (òpìdán) tó ń fẹnu fátẹ́gùn túẹ́túẹ́ sínú àwọn ońdè,

Verse 5

وَمِن شَرِّ حَاسِدٍ إِذَا حَسَدَ

Transliteration wamin sharri ḥāsidin idhā ḥasada

Yoruba àti níbi aburú onílara nígbà tí ó bá ṣe ìlara.”

Read Surah Al-Falaq in another language

All languages

All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.

Learn it in MyDugsi

Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.