MyDugsiStart learning

Surah Al-Qadr in Yoruba: translation and audio

Surah 97 · القدر · The Power · 5 verses

Surah Al-Qadr verse by verse: the Arabic with a recitation you can repeat, the transliteration, and the Yoruba translation by Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni. For the meaning of every word, see Surah Al-Qadr word by word in English.

Verse 1

إِنَّآ أَنزَلْنَـٰهُ فِى لَيْلَةِ ٱلْقَدْرِ

Transliteration innā anzalnāhu fī laylati l-qadri

Yoruba Dájúdájú Àwa sọ al-Ƙur’ān kalẹ̀ nínú Òru Abiyì.1

Verse 2

وَمَآ أَدْرَىٰكَ مَا لَيْلَةُ ٱلْقَدْرِ

Transliteration wamā adrāka mā laylatu l-qadri

Yoruba Kí sì ni ó mú ọ mọ ohun tó ń jẹ́ Òru Abiyì?

Verse 3

لَيْلَةُ ٱلْقَدْرِ خَيْرٌ مِّنْ أَلْفِ شَهْرٍ

Transliteration laylatu l-qadri khayrun min alfi shahrin

Yoruba Òru Abiyì lóore ju ẹgbẹ̀rún oṣù.

Verse 4

تَنَزَّلُ ٱلْمَلَـٰٓئِكَةُ وَٱلرُّوحُ فِيهَا بِإِذْنِ رَبِّهِم مِّن كُلِّ أَمْرٍ

Transliteration tanazzalu l-malāikatu wal-rūḥu fīhā bi-idh'ni rabbihim min kulli amrin

Yoruba Àwọn mọlāika àti Jibrīl yó sì máa sọ̀kalẹ̀ nínú òru náà pẹ̀lú àṣẹ Olúwa wọn fún gbogbo ọ̀rọ̀ ẹ̀dá kọ̀ọ̀kan.

Verse 5

سَلَـٰمٌ هِىَ حَتَّىٰ مَطْلَعِ ٱلْفَجْرِ

Transliteration salāmun hiya ḥattā maṭlaʿi l-fajri

Yoruba Àlàáfíà ni òru náà títí di àsìkò àfẹ̀mọ́júmọ́.

Read Surah Al-Qadr in another language

All languages

All 114 surahs in Yoruba: the Qur’an in Yoruba.

Learn it in MyDugsi

Yoruba translation: Shaykh Abu Rahimah Mikael Aykyuni, from Quran.com. Transliteration: Quran.com. Recitation: Mishary Alafasy, from EveryAyah.com. MyDugsi is a learning aid, not a replacement for a qualified teacher.